Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 49:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ohun tí Olúwa wí níyìí:“Bẹ́ẹ̀ ni, a ó gba àwọn ìgbékùn lọ́wọ́ àwọn jagunjagun,àti ìkógun lọ́wọ́ àwọn akíkanjú;Ẹni tí ó bá ọ jà ni èmi ó bá jà,àti àwọn ọmọ rẹ ni èmi ó gbàlà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:25 ni o tọ