Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 45:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ kó ara yín jọ kí ẹ sì wá;ẹ kórajọ, ẹ̀yin ìṣáǹṣá láti àwọnọrílẹ̀ èdè wá.Aláìmọ̀kan ni àwọn tí ó ń ru ère igi káàkiri,tí wọ́n gbàdúrà sí àwọn òrìṣà tí kò le gba ni.

Ka pipe ipin Àìsáyà 45

Wo Àìsáyà 45:20 ni o tọ