Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 44:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Alágbẹ̀dẹ mú ohun èlò,ó fi ń ṣiṣẹ́ nínú èédú;ó fi òòlù ya ère kan,ó ṣe é pẹ̀lú agbára apá rẹ̀,Ebi ń pa á, àárẹ̀ sì mú un;kò mu omi rárá, ìrẹ̀wẹ̀sì dé bá a.

Ka pipe ipin Àìsáyà 44

Wo Àìsáyà 44:12 ni o tọ