Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 44:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun àti nǹkan rẹ̀ wọ̀nyí ni a ó dójú tì;àwọn oníṣọ̀nà kò yàtọ̀, ènìyàn ni wọ́n.Jẹ́ kí gbogbo wọn gbárajọ kí wọ́n sìfi ìdúró wọn hàn;gbogbo wọn ni a ó mú bọ́ sínú Ìpayà àti àbùkù.

Ka pipe ipin Àìsáyà 44

Wo Àìsáyà 44:11 ni o tọ