Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 44:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbẹ́nàgbẹ́nà fi ìwọ̀n wọ̀n ọ́nó sì fi lẹ́ẹ̀dì ṣe àmì sí ara rẹ̀,Ó tún fi ṣísẹ́lì họ ọ́ jádeó tún fi kọ́ḿpáásì ṣe àmì sí i.Ó gbẹ́ ẹ ní ìrí ènìyàngẹ́gẹ́ bí ènìyàn nínú ògo rẹ̀,kí ó lè máa gbé nínú ilé òrìṣà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 44

Wo Àìsáyà 44:13 ni o tọ