Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 4:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ní ọjọ́ náà, obìnrin méjeyóò dì mọ́ ọkunrin kanyóò sì wí pé, “Àwa ó má a jẹ oúnjẹ ara waa ó sì pèsè aṣọ ara wa;sáà jẹ́ kí a má a fi orúkọ rẹ̀ pè wá.Mú ẹgan wá kúrò!”

2. Ní ọjọ́ náà, ẹ̀ka Olúwa yóò ní ẹwà àti ogo, èso ilẹ̀ náà yóò sì jẹ́ ìgbéraga àti ògo àwọn ti ó sálà ní Ísírẹ́lì.

3. Àwọn tí ó ṣẹ́kù ní Síhónì, àwọn tí o kù ní Jérúsálẹ́mù, ni a ó pè ní mímọ́, orúkọ àwọn ẹni tí a kọ mọ́ àwọn alààyè ní Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin Àìsáyà 4