Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ náà, obìnrin méjeyóò dì mọ́ ọkunrin kanyóò sì wí pé, “Àwa ó má a jẹ oúnjẹ ara waa ó sì pèsè aṣọ ara wa;sáà jẹ́ kí a má a fi orúkọ rẹ̀ pè wá.Mú ẹgan wá kúrò!”

Ka pipe ipin Àìsáyà 4

Wo Àìsáyà 4:1 ni o tọ