Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 39:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó sọ dára,” ni èsì Heṣekáyà. Nítorí ó rò nínú ara rẹ̀ pé, “Àlàáfíà àti ààbò yóò wà ní Ìgbà ayé tèmi.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 39

Wo Àìsáyà 39:8 ni o tọ