Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 38:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ náà ni Heṣekáyà ṣe àìṣàn dé ojú ikú. Wòlíì Àìṣáyà ọmọ Ámósì sì lọ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀, ó sì wí pé, “Ohun tí Olúwa wí nìyìí: palẹ̀ iléẹ̀ rẹ mọ́, bí ó ti yẹ nítorí pé ìwọ yóò kú; ìwọ kì yóò dìde àìṣàn yìí.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 38

Wo Àìsáyà 38:1 ni o tọ