Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 37:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ sọ fún Heṣekáyà ọba Júdà pé: Má ṣe jẹ́ kí òrìṣà tí ìwọ gbẹ́kẹ̀lé tàn ọ́ jẹ nígbà tí ó sọ pé, ‘a kì yóò jọ̀wọ́ Jérúsálẹ́mù fún ọba Ásíríà.’

Ka pipe ipin Àìsáyà 37

Wo Àìsáyà 37:10 ni o tọ