Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 37:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àkókò yìí Ṣenakérúbù gbọ́ ìròyìn kan pé Tíhákà ará Kúṣì ọba Éjíbítì ń jáde bọ̀ wá bá òun jà. Nígbà tí ó gbọ́ èyí, ó rán oníṣẹ́ sí Heṣekáyà pẹ̀lú ọ̀rọ̀ wọ̀nyí:

Ka pipe ipin Àìsáyà 37

Wo Àìsáyà 37:9 ni o tọ