Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 37:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dájúdájú, ìwọ ti gbọ́ ohun tí ọba Ásíríà ti ṣe sí àwọn orílẹ̀ èdè, tí ó pa wọ́n run pátapáta. Ǹjẹ́ a ó ha dá ọ nídè bí?

Ka pipe ipin Àìsáyà 37

Wo Àìsáyà 37:11 ni o tọ