Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 35:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yanrìn tí ń jóná yóò di adágúnilẹ̀ tí ń pòǹgbẹ yóò di orísun omi.Òpópó ibi tí àwọn ajáko sùn tẹ́lẹ̀ríkoríko àti koríko odò àti ewéko mìíràn yóò hù níbẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 35

Wo Àìsáyà 35:7 ni o tọ