Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 35:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni àwọn arọ yóò máa fò bí àgbọ̀nrín,àti ahọ́n odi yóò ké fún ayọ̀.Odò yóò tú jáde nínú ihààti àwọn odò nínú aṣálẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 35

Wo Àìsáyà 35:6 ni o tọ