Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 34:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ wá a nínú ìwé Olúwa, ẹ sì kà á:Ọ̀kan nínú wọ̀nyí kì yóò yẹ̀,kò sí ọ̀kan tí yóò fẹ́ ìkejìi rẹ̀ kù:nítorí Olúwa ti pàṣẹẹnu rẹ̀ ló sì fi kó wọn jọẸ̀mí rẹ̀ ló sì fi tò wọ́n jọ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 34

Wo Àìsáyà 34:16 ni o tọ