Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 34:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ti di ìbò fún wọn,ọwọ́ rẹ̀ sì ti pín in fún wọnnípa títa okùn,wọn ó jogún rẹ̀ láéláé,láti ìran dé ìranni wọn ó máa gbé inú un rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 34

Wo Àìsáyà 34:17 ni o tọ