Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 34:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òwìwí yóò tẹ́ ìtẹ́ rẹ̀ ṣíbẹ̀,yóò yé, yóò sì pa,yóò sì kójọ lábẹ́ òjìji rẹ̀:àwọn gúnnugún yóò péjọ ṣibẹ̀ pẹ̀lú,olúkúlùkù pẹ̀lú ẹnìkejì rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 34

Wo Àìsáyà 34:15 ni o tọ