Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 33:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbójú ṣókè sí Ṣíhónì, ìlú àjọ̀dún wa,ojú rẹ yóò rí Jérúsálẹ́mù,ibùgbé àlàáfíà nnì, àgọ́ tí a kò ní yí padà;àwọn òpó rẹ̀ ni a kì yóò fàtutàbí èyíkéyìí nínú okùn rẹ̀ kí já.

Ka pipe ipin Àìsáyà 33

Wo Àìsáyà 33:20 ni o tọ