Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 33:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ kì yóò rí àwọn agbéraga ènìyàn wọ̀nyẹn mọ́,àwọn ènìyàn tí èdè wọn farasin,pẹ̀lú ahọ́n tí ó ṣàjèjì tí kò sì yéni.

Ka pipe ipin Àìsáyà 33

Wo Àìsáyà 33:19 ni o tọ