Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 33:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbẹ̀ ni Olúwa yóò ti jẹ́ Alágbára kan fún wa.Yóò sì dàbí ibi àwọn odò ńlá ńlá àti odò kéékèèkéé.Kì yóò sí ọkọ̀ ojú omi pẹ̀lú tí yóò kọjá lóríi wọn,ọkọ̀ ojú omi ńlá ni a kì yóò tù lórí wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 33

Wo Àìsáyà 33:21 ni o tọ