Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 31:8-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

8. “Ásíríà yóò ṣubú lọ́wọ́ idà kan tí kò ti ọwọ́ ènìyàn wá;idà tí kì í ṣe ti ẹ̀dá alààyè ni yóò pa wọ́n.Wọn yóò sì sá níwájú idà náààti àwọn ọmọkùnrin wọn ni a ó fún ní iṣẹ́ ipá ṣe.

9. Ibi gíga wọn ni yóò wó lulẹ̀ nítorí ìpayà;nípa ìrísí agbára ogun wọn, àwọnọ̀gágun wọn yóò wárìrì,”ni Olúwa wí,ẹni tí iná rẹ̀ ń bẹ ní Ṣíhónì,ẹni tí ìléru rẹ̀ wà ní Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin Àìsáyà 31