Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 31:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ásíríà yóò ṣubú lọ́wọ́ idà kan tí kò ti ọwọ́ ènìyàn wá;idà tí kì í ṣe ti ẹ̀dá alààyè ni yóò pa wọ́n.Wọn yóò sì sá níwájú idà náààti àwọn ọmọkùnrin wọn ni a ó fún ní iṣẹ́ ipá ṣe.

Ka pipe ipin Àìsáyà 31

Wo Àìsáyà 31:8 ni o tọ