Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 30:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èémíi rẹ̀ sì dàbí òjò alágbára,tí ó rú sókè dé ọ̀run.Ó jọ àwọn orílẹ̀ èdè nínú asẹ́ ìparun;ó sì fi sí àgbọ̀n àwọn ènìyànkókó kan tí ó ń sì wọ́n lọ́nà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 30

Wo Àìsáyà 30:28 ni o tọ