Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 30:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kíyèsí i, orúkọ Olúwa ti òkèèrè wápẹ̀lú ìbínú gbígbóná àti kùrukùruèéfín tí ó nípọn;ètè rẹ̀ kún fún ìbínúahọ́n rẹ̀ sì jẹ́ iná ajónirun.

Ka pipe ipin Àìsáyà 30

Wo Àìsáyà 30:27 ni o tọ