Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 30:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òṣùpá yóò sì tàn bí òòrùn, àti ìtànsán òòrùn yóò mọ́lẹ̀ ní ìlọ́po méje, gẹ́gẹ́ bí ìmọ́lẹ̀ odidi ọjọ́ méje, nígbà tí Olúwa yóò di ojú ọgbẹ́ àwọn ènìyàn an rẹ̀ tí yóò sì wo ọgbẹ́ tí ó ti dá sí wọn lára sàn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 30

Wo Àìsáyà 30:26 ni o tọ