Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 30:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ yóò sọ ẹ̀míi wọn nù nígbà tí ilé ìṣọ́ yóò wó lulẹ̀, odò omi yóò ṣàn lórí òkè gíga àti lórí àwọn òkè kékeré.

Ka pipe ipin Àìsáyà 30

Wo Àìsáyà 30:25 ni o tọ