Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 29:2-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

2. Ṣíbẹ̀ ṣíbẹ̀ èmi yóò dó ti Áríẹ́lìòun yóò ṣọ̀fọ̀ yóò sì sunkún,òun yóò sì dàbí pẹpẹ ọkàn sí mi.

3. Èmi yóò sì wà ní bùba yí ọ ká níbi gbogbo;Èmi yóò sì fi ilé-ìṣọ́ yí ọ ká:èmi yóò sì fi iṣẹ́ ìdótini mi dojú kọ ọ́.

4. Ní ìrẹ̀sílẹ̀, ìwọ ó sì máa sọ̀rọ̀ láti ilẹ̀ wá;ọ̀rọ̀ rẹ yóò sì máa kùn jáde láti inú erùpẹ̀.Ohun rẹ yóò máa jáde bí i ti iwin láti ilẹ̀ wá,láti inú erùpẹ̀ ni ohùn rẹyóò máa wá wúyẹ́wúyẹ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 29