Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 29:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìrẹ̀sílẹ̀, ìwọ ó sì máa sọ̀rọ̀ láti ilẹ̀ wá;ọ̀rọ̀ rẹ yóò sì máa kùn jáde láti inú erùpẹ̀.Ohun rẹ yóò máa jáde bí i ti iwin láti ilẹ̀ wá,láti inú erùpẹ̀ ni ohùn rẹyóò máa wá wúyẹ́wúyẹ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 29

Wo Àìsáyà 29:4 ni o tọ