Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 29:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún un yín gbogbo ìran yìí kò yàtọ̀ sí àwọn ọ̀rọ̀ tí a fi èdìdì dì sínú ìwé kíká. Bí ẹ bá sì fún ẹni tí ó lè ka ìwé kíká náà, tí ẹ sì sọ fún un pé, “Jọ̀wọ́ ka èyí,” òun yóò dáhùn pé, “Èmi kò lè kà á; a ti dì í ní èdìdì.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 29

Wo Àìsáyà 29:11 ni o tọ