Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 28:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ fọ́n pé, “Àwa ti bá ikú mulẹ̀,pẹ̀lú ibojì ni àwa ti jọ ṣe àdéhùn.Nígbà tí ìbáwí gbígbóná fẹ́ kọjá,kò le kàn wá lára,nítorí a ti fi irọ́ ṣe ààbò o waàti àìṣòtítọ́ ibi ipamọ́ wa.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 28

Wo Àìsáyà 28:15 ni o tọ