Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 28:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ìdí náà èyí ni ohun tí Olúwa Jèhófà sọ:“Kíyèsíì, mo gbé òkúta kan lélẹ̀ ní Ṣíhónìòkúta tí a dánwò,òkúta igunlé iyebíye fún ìpìlẹ̀ tí ó dájúẹnikẹ́ni tí ó bá gbẹ́kẹ̀le kì yóò ní ìfòyà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 28

Wo Àìsáyà 28:16 ni o tọ