Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 25:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ori òkè yìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogunyóò ti pèṣèàṣè oúnjẹ àdídùn kan fún gbogbo ènìyànàpèjẹ ti wáìnì àtijọ́ti ẹran tí ó dára jù àti ti wáìnìtí ó gbámúṣé.

Ka pipe ipin Àìsáyà 25

Wo Àìsáyà 25:6 ni o tọ