Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 25:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àti gẹ́gẹ́ bí ooru ní ihà.O mú ìdákẹ́ jẹ́ẹ́ bá rògbòdìyàn àwọn àjèjì,gẹ́gẹ́ bí òjìji kùrukùru ṣe ń dín ooru kù,bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni orin àwọn ìkà yóò dákẹ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 25

Wo Àìsáyà 25:5 ni o tọ