Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni yóò wá, wọn ó si sọ pé“Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á gòkè lọsí òkè Olúwa,sí ilé Ọlọ́run Jákọ́bù.Òun yóò kọ́ wa ní ọ̀nà rẹ̀,kí àwa kí ó lè rìn ní ọ̀nà rẹ̀.”Òfin yóò jáde láti Síhónì wá,àti ọ̀rọ̀ Olúwa láti Jérúsálẹ́mù wá.

Ka pipe ipin Àìsáyà 2

Wo Àìsáyà 2:3 ni o tọ