Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ó ṣe ìdájọ́ láàárin àwọn orílẹ̀ èdèyóò sì parí aáwọ̀ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn.Wọn yóò fi idà wọn rọ ọkọ́ ìtulẹ̀wọn yóò sì fi ọ̀kọ̀ wọn rọ dòjé.Orílẹ̀ èdè kì yóò sì gbé idà sí orílẹ̀ èdè mọ́,bẹ́ẹ̀ ní wọn kì yóò kọ́ ogun jíjà mọ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 2

Wo Àìsáyà 2:4 ni o tọ