Ní ìgbẹ̀yìn ọjọ́òkè tẹ́ḿpìlì Olúwani a ó fi ìdí rẹ̀ kalẹ̀gẹ́gẹ́ bí olú nínú àwọn òkè,a ó sì gbé e ga ju àwọn òkè kékeré lọ,gbogbo orílẹ̀ èdè yóò sì máa ṣàn sínú un rẹ̀.