Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 18:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

tí ó rán àwọn ikọ̀ lórí òkunlórí omi nínú ọkọ̀-ọpọ́n tí a fi kóríko ṣe.Ẹ lọ, ẹ̀yin ikọ̀ tí ó yára,sí àwọn ènìyàn gíga tí àwọ̀-ara wọn jọ̀lọ̀,sí àwọn ènìyàn tí a ń bẹ̀rù káàkiri,orílẹ̀ èdè aláfojúdi alájèjì èdè,tí odò pín ilẹ̀ rẹ̀ yẹ́lẹyẹ̀lẹ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 18

Wo Àìsáyà 18:2 ni o tọ