Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 12:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ náà ìwọ ó wí pé:“Èmi ó yìn ọ́, Olúwa.Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé ò ti bínú sí miìbínú rẹ ti yí kúrò níbẹ̀ìwọ sì ti tù mí nínú.

Ka pipe ipin Àìsáyà 12

Wo Àìsáyà 12:1 ni o tọ