Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 12:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítòótọ́ Ọlọ́run ni ìgbàlà mi,Èmi yóò gbẹ́kẹ̀lé e èmi kì yóò bẹ̀rù. Olúwa, Olúwa náà ni agbára à mi àti orin ìn mi,òun ti di ìgbàlà mi.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 12

Wo Àìsáyà 12:2 ni o tọ