Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 11:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò gbé àṣíá sókè fún àwọn orílẹ̀ èdè,yóò sì kó àwọn ìgbèkùn Ísírẹ́lì jọ,yóò kó gbogbo àwọn ènìyàn Júdà tí a ti fọ́n káàkiri jọ,láti igun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ilẹ̀ ayé.

Ka pipe ipin Àìsáyà 11

Wo Àìsáyà 11:12 ni o tọ