Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 1:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nigbà tí ẹ bá tẹ́ ọwọ́ yín sóke ni àdúrà,Èmi yóò fi ojú mi pamọ́ fún un yín,kódà bí ẹ bá gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àdúrà,Èmi kò ni tẹ́ti sí i.Ọwọ́ yín kún fún ẹ̀jẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 1

Wo Àìsáyà 1:15 ni o tọ