Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 1:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ayẹyẹ oṣù tuntun yín àti àpèjẹtí ẹ yà ṣọ́tọ̀ni ọkàn mi kórìíra.Wọ́n ti di àjàgà sí mi ní ọrùn,Ó ti sú mi láti máa fara dà wọ́n.

Ka pipe ipin Àìsáyà 1

Wo Àìsáyà 1:14 ni o tọ