Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 10:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn olórí àwọn ọmọ Ámónì sì wí fún Hánúnì Olúwa wọn pé, “Ǹjẹ́ o rò pé Dáfídì ń bu ọlá fún baba rẹ nígbà tí ó rán ènìyàn wá láti bá ọ kẹ́dùn? Kò ha ṣe pé Dáfídì rán àwọn ìránṣẹ́ sí ọ láti wo ìlú àti láti yọ́ ọ wò àti láti gbà ọ́.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 10

Wo 2 Sámúẹ́lì 10:3 ni o tọ