Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 8:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hásáélì sì wí pé. “Báwo ni ìránṣẹ́ rẹ, ajá lásán làsàn yóò ṣe ṣe irú nǹkan ńlá bẹ́ẹ̀?”“Olúwa ti fi hàn mí pé ìwọ ni yóò jẹ ọba síríà,” Èlíṣà dá a lóhùn.

Ka pipe ipin 2 Ọba 8

Wo 2 Ọba 8:13 ni o tọ