Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 8:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kí ni ó dé tí Olúwa mi fi ń sunkún?” Hásáélì bèèrè.“Nítorí pé èmi mọ ibi tí ìwọ yóò ṣe sí Ísírẹ́lì,” ó sì dáhùn pé, “Ìwọ yóò fi iná si odi agbára wọn, ìwọ yóò, pa àwọn ọ̀dọ́ ọmọkùnrin wọn pẹ̀lú idà, ìwọ yóò kọlù àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ wọn, ìwọ ó sì fọ́ wọn túútúú, ìwọ o sì la inú àwọn aboyún wọn.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 8

Wo 2 Ọba 8:12 ni o tọ