Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 7:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìjòyè kan ẹni tí ọwọ́ ọba ń fi ara tì dáhùn wí fún ènìyàn Ọlọ́run pé, “Ẹ wòó, tí Olúwa bá tilẹ̀ sí fèrèsé ọ̀run sílẹ̀, ṣé èyí lè rí bẹ́ẹ̀?”“Ìwọ yóò rí i pẹ̀lú ojú rẹ,” Èlíṣà dáhùn, “ṣùgbọ́n ìwọ kò ní jẹ nǹkankan lára rẹ̀!”

Ka pipe ipin 2 Ọba 7

Wo 2 Ọba 7:2 ni o tọ