Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 7:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èlíṣà wí pé, “Gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa. Èyí ni ohun tí Olúwa sọ: Ní àsìkò yìí ní ọ̀la, a ó ta òṣùwọ̀n ìyẹ̀fun kíkúná kan ní ṣékélì kan àti méjì òṣùwọ̀n ọkà fún ṣékélì kan ní ẹnu bodè Samáríà.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 7

Wo 2 Ọba 7:1 ni o tọ