Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 5:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Námánì wí pé, “Ní gbogbo ọ̀nà, mú ẹ̀bùn méjì.” Ó sì rọ Géhásì láti gbà wọ́n, ó sì di ẹ̀bùn méjì náà ti fàdákà ní inú àpò méjì, pẹ̀lú ìpààrọ̀ aṣọ méjì, ó sì fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ méjì, wọ́n sì kó wọn lọ sọ́dọ̀ Géhásì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 5

Wo 2 Ọba 5:23 ni o tọ