Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 5:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gbogbo nǹkan wà dáadáa,” Géhásì dá a lóhùn. “Ọ̀gá mi rán mi láti sọ wí pé, ‘Àwọn ọ̀dọ́ ọmọkùnrin méjì láti ọ̀dọ̀ ọmọ wòlíì wọ́n ṣẹ̀ ṣẹ̀ wá sí ọ̀dọ̀ mi láti orí òkè ìlú ti Éfúráímù. Jọ̀wọ́ fún wọn ní ẹ̀bùn fàdákà àti ìpàrọ̀ aṣọ méjì.’ ”

Ka pipe ipin 2 Ọba 5

Wo 2 Ọba 5:22 ni o tọ