Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 5:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Géhásì wá sí ilẹ̀ gíga, ó sì mú nǹkan náà lọ́dọ̀ ìránṣẹ́ ó sì gbé wọn kúrò ní ilé, ó sì rán ọkùnrin náà jáde ó sì lọ.

Ka pipe ipin 2 Ọba 5

Wo 2 Ọba 5:24 ni o tọ